Ko S’ore bi Jesu Onirele

 


1.Ko s’ore bi Jesu onirele
Ko s’ ore bi ti Re
Ko s’ onisegun to le w’ese san
Ko s’ ore bi ti Re


Ref
Jesu mo gbogbo ‘jakadi wa
Y’o ran wa lowo de opin
Ko s’ ore bi Jesu onirele
Ko s’ ore bi ti Re


2.Kos’ ore to ga bi Re ni mimo
Ko s’ ore bi ti Re
Ko s’ ore to n’irele bi ti Re
Ko s’ ore bi ti Re


3.Ko s’ akoko kan ti ko sunmo wa
Ko s’ ore bi ti Re
Ninu ‘danwo y’o ma tu wa ninu
Ko s’ ore bi ti Re


4. Ebun kan ha wa to ju Jesu lo?
Ko s’ ore bi ti Re
Y’o ha ko fun wa k’a n’ile l’orun?
Ko je ko! Ko je ko!

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *