Fa Mi Sunmo Agbelebu

 


Ese Kini Fa Mi Sunmo Agbelebu,
Orisun Iwosan
Itunu fun elese
Iye f’eni nku lo.


Egbe:
Agbelebu Kristi,
Ni y’o je ogo mi;
Titi ngo fi goke lo
S’ibi isimi mi.


Ese Keji Nib’ Agbelebu mo ri,
Anu ife Jesu;
Nibe I’Orun ododo,
Ti ran si okan mi.


Ese Keta Nib’ Agbelebu mo ri,
Odagutan t’a pa,
‘Jojumo ran mi leti,
Ijiya kalfari.


Ese Kerin Ki ngbadura, ki nsora
Nibi Agbelebu,
Ki iranti ife Re,
Ma fi mi ‘le titi.


Ese Kini(versionB)
Nib ‘Agbelebu Jesu
Lori sun ‘yebiye
Ati omi iwosan
San like kalfari.


Egbe:(versionB)
Ninu Agbelebu
Le mi o sogo lai.
Titi okan mi yo sinmi
Lehin odo naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *